Mátíù 25:38 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tàbí tí o jẹ́ àlejò tí a gbà ó sínú ilé wa? Tàbí tí o wà ní ìhòòhò, tí a sì daṣọ bò ọ́?

Mátíù 25

Mátíù 25:34-41