Mátíù 25:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo orílẹ̀-èdè ni a ó kó jọ níwájú rẹ̀, òun yóò sì ya àwọn ènìyàn ayé sí ọ̀tọ̀ gẹ́gẹ́ bí olùṣọ́ àgùntàn ṣe é ya àgùntàn kúrò lára àwọn ewúrẹ́.

Mátíù 25

Mátíù 25:22-33