Mátíù 25:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí ẹnikẹ́ni tí ó bá ní a ó fún sí i, yóò sí tún ní sí lọ́pọ̀lọpọ̀. Ṣùgbọ́n láti ọwọ́ ẹni tí kò ní ni a ó ti gbà èyí tí ó ní.

Mátíù 25

Mátíù 25:28-30