Mátíù 25:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Olúwa rẹ̀ wí fún un pé, ‘O ṣeun ìwọ ọmọ-ọ̀dọ̀ rere àti olóòótọ́: ìwọ ṣe olóòótọ́ nínú ohun díẹ̀, èmi yóò fi ọ́ ṣe olórí ohun púpọ̀, bọ́ sínú ayọ̀ olúwa rẹ.’

Mátíù 25

Mátíù 25:15-23