Mátíù 25:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“A sì tún fi ìjọba ọ̀run wé ọkùnrin kan tí ó ń lọ sí ìrìn-àjò. Ó pe àwọn ọmọ-ọ̀dọ̀ rẹ̀, ó sì kó ohun ìní rẹ̀ fún wọn.

Mátíù 25

Mátíù 25:8-19