Mátíù 24:49 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tí ó sì bẹ̀rẹ̀ si í fi ìyà jẹ́ àwọn ìránṣẹ́ ẹlẹgbẹ́ rẹ̀, tí ó ń jẹ, tí ó sì ń mu àmupara.

Mátíù 24

Mátíù 24:41-51