Mátíù 24:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ó ti jókòó ní orí òkè Ólífì, àwọn ọmọ-ẹ̀yìn tọ̀ ọ́ wá ní kọ̀kọ̀, wọ́n wí pé, “Sọ fún wa nígbà wo ni èyí yóò ṣẹlẹ̀? Kí ni yóò jẹ́ àmì ìpadàwá rẹ, àti ti òpin ayé?”

Mátíù 24

Mátíù 24:1-9