Mátíù 24:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ẹni tí ó wà lórí ilé rẹ̀ má ṣe sọ̀ kalẹ̀ wá mú ohunkóhun jáde nínú ilé rẹ̀.

Mátíù 24

Mátíù 24:11-19