Mátíù 23:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti pé, ẹ̀yin ń tẹ̀lé ìṣísẹ̀ àwọn baba yín. Ẹ̀yin ń kún òsùwọ̀n ìwà búburú wọn dé òkè.

Mátíù 23

Mátíù 23:31-33