Mátíù 23:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ̀yin gbìyànjú láti fara hàn bí ènìyàn mímọ́, olódodo, lábẹ́ aṣọ mímọ́ yínni ọkàn tí ò kún fún ìbàjẹ́ pẹ̀lú oríṣìíríṣìí àgàbàgebè àti ẹ̀ṣẹ̀ wà.

Mátíù 23

Mátíù 23:25-31