Mátíù 23:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí a má sì ṣe pè yín ní Olùkọ́ nítorí Olùkọ́ kan ṣoṣo ni ẹ̀yin ní, òun náà ni Kírísítì.

Mátíù 23

Mátíù 23:8-13