Mátíù 22:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba yìí bínú gidigidi, ó sì rán àwọn ọmọ-ogun rẹ̀, ó sì pa àwọn apànìyàn náà run, ó sì jó ìlú wọn

Mátíù 22

Mátíù 22:1-12