Mátíù 22:42 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Kí ni ẹ rò nípa Kírísítì? Ọmọ ta ni òun ń ṣe?”Wọ́n dáhùn pé, “Ọmọ Dáfídì.”

Mátíù 22

Mátíù 22:35-46