Mátíù 20:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àánú wọn sì ṣe Jésù, ó fi ọwọ́ kan ojú wọn. Lójú kan náà, wọ́n sì ríran, wọ́n sì ń tọ̀ ọ́ lẹ́yìn.

Mátíù 20

Mátíù 20:25-34