Mátíù 20:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ṣùgbọ́n ó dá ọ̀kan nínú wọn lóhùn pé, ‘Ọ̀rẹ́, kò sí aburú nínú nǹkan tí èmi ṣe sí yín. Kì í ha ṣe pé ẹ̀yin gbà láti ṣiṣẹ́ fún owó dínárì kan.

Mátíù 20

Mátíù 20:10-20