Mátíù 19:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù sì tẹjú mọ́ wọn, ó wí pé, “Bí o bá jẹ́ ti ènìyàn ni, eléyìí sòro. Ṣùgbọ́n bí ó bá ṣe ti Ọlọ́run ni, ohun gbogbo ni ṣíṣe.”

Mátíù 19

Mátíù 19:22-27