Mátíù 19:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo tún wí fún yín pé, “Ó rọrùn fún ràkúnmí láti wọ ojú abẹ́rẹ́ jù fún ọlọ́rọ̀ láti wọ ìjọba Ọlọ́run.”

Mátíù 19

Mátíù 19:21-27