Mátíù 18:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ojú rẹ yóò bá sì mú kí o dẹ́sẹ̀, yọ ọ́ kúrò kí ó sì sọ ọ́ nù. Ó kúkú sàn fún ọ láti wọ ìjọba ọ̀run pẹ̀lú ojú kan, ju pé kí o ní ojú méjì, kí a sì jù ọ́ sí iná ọ̀run àpádì.

Mátíù 18

Mátíù 18:1-12