Mátíù 18:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù dáhùn pé, “Mo wí fún ọ, kì í se ìgbà méje, ṣùgbọ́n ní ìgbà àádọ́rin méje;

Mátíù 18

Mátíù 18:12-24