Mátíù 17:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pétérù dáhùn pé, “Lọ́wọ́ àwọn àlejò ni.”Jésù sì tún wí pé, “Èyí jẹ́ wí pé àwọn ọmọ onílẹ̀ kì í san owó-òde?

Mátíù 17

Mátíù 17:25-27