Mátíù 15:37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo wọn jẹ, wọ́n sì yó. Lẹ́yìn náà, àwọn ọmọ-ẹ̀yìn sì sa èyí tókù, ẹ̀kún agbọ̀n méje ni èyí tó sẹ́kù jẹ́

Mátíù 15

Mátíù 15:32-39