Mátíù 14:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà ti wọn mọ̀ pé Jésù ni, wọn sì ránṣẹ́ sí gbogbo ìlú náà yíká. Wọ́n sì gbé gbogbo àwọn aláìsàn tọ̀ ọ́ wá.

Mátíù 14

Mátíù 14:25-36