Mátíù 13:47 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Bákan náà, a sì tún lè fi ìjọba ọ̀run wé àwọ̀n kan tí a jù sínú odò, ó sì kó onírúurú ẹja.

Mátíù 13

Mátíù 13:41-48