Mátíù 13:44 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ìjọba ọ̀run sì dàbí ìṣúra kan tí a fi pamọ́ sínú oko. Nígbà tí ọkùnrin kan rí i ó tún fi í pamọ́. Nítorí ayọ̀ rẹ̀, ó ta gbogbo ohun ìní rẹ̀, ó ra oko náà.

Mátíù 13

Mátíù 13:39-47