Mátíù 1:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sálímónì ni baba Bóásì, Ráhábù sí ni ìyá rẹ̀;Bóásì ni baba Óbédì, Rúùtù sí ni ìyá rẹ̀;Óbédì sì ni baba Jésè;

Mátíù 1

Mátíù 1:1-9