Máàkù 9:47 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti pé, bí ojú rẹ bá mú ọ kọsẹ̀, yọ ọ́ sọnù, ó sàn kí o wọ ìjọba Ọlọ́run pẹ̀lú ojú kan ju kí ó ní ojú méjì kí ó sì lọ sí inú iná ọ̀run àpáàdì.

Máàkù 9

Máàkù 9:40-50