Máàkù 9:37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ẹnikẹ́ni tí ó bá tẹ́wọ́gba ọmọ kékeré bí èyí ní orúkọ mi, òun gbà mí. Ẹnikẹ́ni tí ó bá sì gbà mi, ó gba Baba mi, tí ó rán mi.”

Máàkù 9

Máàkù 9:27-45