Máàkù 9:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n Jésù fà á lọ́wọ́, ó sì ràn án lọ́wọ́ láti dúró lórí ẹsẹ̀ rẹ̀. Ó díde dúró.

Máàkù 9

Máàkù 9:25-34