Máàkù 8:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù sì rán an sí àwọn ẹbí rẹ̀. Ó kìlọ̀ fún un pé, “Má ṣe lọ sí ìlú, kí o má sì sọ fún ẹnikẹni ní ìlú.”

Máàkù 8

Máàkù 8:19-34