Máàkù 7:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

(Àwọn Farisí, àti gbogbo àwọn Júù, bí wọ́n kò bá wẹ ọwọ́ wọn gidigidi, wọn kií jẹun nítorí wọ́n ti pa òfin àtọwọdọ́wọ́ àwọn àgbà mọ́.

Máàkù 7

Máàkù 7:1-7