Máàkù 6:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọmọbìnrin yìí sáré padà wá sọ́dọ̀ Hẹ̀rọ́dù ọba. Ó sì wí fún un pé, “Mo ń fẹ́ orí Jòhánù Onítẹ̀bọmi nísinsin-yìí nínú àwopọ̀kọ́.”

Máàkù 6

Máàkù 6:22-29