Máàkù 5:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù sì bi í léèrè pé, “Kí ni orúkọ rẹ?”Ẹ̀mí àìmọ́ náà sì dáhùn wí pé, “Líjíọ́nì, nítorí àwa pọ̀.”

Máàkù 5

Máàkù 5:1-10