Máàkù 5:43 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù sì kìlọ̀ fún wọn gidigidi pé kí wọn má ṣe sọ ohun tí ó ti ṣẹlẹ̀. Ó sì wí fún wọn kí wọn fún ọmọbìnrin náà ní oúnjẹ.

Máàkù 5

Máàkù 5:37-43