Máàkù 5:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí pé nígbà púpọ̀ ni wọn ti ń fi ṣẹ́kẹ́sẹkẹ̀ dè é lọ́wọ́ àti ẹṣẹ̀, tí ó sì ń já a dànù kúrò ni ẹṣẹ rẹ. Kò sí ẹnìkan tí ó ní agbára láti káwọ́ rẹ̀.

Máàkù 5

Máàkù 5:1-6