Máàkù 5:39 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó wọ inú ilé lọ, Ó sì bá àwọn ènìyàn sọ̀rọ̀, ó béèrè pé, “Èéṣe tí ẹ̀yin fi ń sọkún tí ẹ sì ń pohunréré ẹkún? Ọmọbìnrin náà kò kú, ó sùn lásán ni.”

Máàkù 5

Máàkù 5:37-40