Máàkù 5:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù kò gbà fún un, ṣùgbọ́n ó wí fún un pé, “Lọ sí ilé sí ọ̀dọ̀ àwọn ẹbí rẹ, kí o sì sọ fún wọn bí Ọlọ́run ti ṣe ohun ńlá fún ọ, àti bí ó sì ti ṣàánú fún ọ.”

Máàkù 5

Máàkù 5:18-29