Máàkù 4:38 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù ti sùn lọ lẹ́yìn ọkọ̀, ó gbé orí lé ìrọ̀rí. Wọ́n sì jí i lóhùn rara wí pé, “Olùkọ́ni, tàbí ìwọ kò tilẹ̀ bìkítà pé gbogbo wa fẹ́ rì?”

Máàkù 4

Máàkù 4:28-39