Máàkù 4:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lóru àti ní ọ̀sán, bóyá ó sùn tàbí ó dìdè, irúgbìn náà hù jáde, ó sì dàgbà, òun kò sì mọ̀ bí ó ti ṣẹlẹ̀.

Máàkù 4

Máàkù 4:24-37