Máàkù 4:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bákan náà, àwọn tí ó bọ́ sórí àpata, ni àwọn ènìyàn tí wọ́n fi ayọ̀ gbọ́ ọ̀rọ̀ Ọlọ́run.

Máàkù 4

Máàkù 4:12-22