Máàkù 15:40 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn obìnrin kan wà níbẹ̀ pẹ̀lú, tí wọ́n ń najú wò ó láti òkèèrè. Màríà Magidalénì wà lára àwọn obìnrin náà, àti Màríà ìyá Jákọ́bù kékeré àti ti Jósè àti, Ṣálómè.

Máàkù 15

Máàkù 15:39-46