Máàkù 15:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pílátù sì tún bi í léèrè pé, “Ṣe ìwọ kò dáhùn ni? Wo gbogbo ẹ̀sùn tí wọ́n fi kàn ọ.”

Máàkù 15

Máàkù 15:1-14