Máàkù 15:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn sì fi aṣọ aláwọ̀ àlùkò wọ̀ ọ́, wọ́n hun adé ẹ̀gún, wọ́n sì fi dé e ní orí.

Máàkù 15

Máàkù 15:8-18