Máàkù 14:54 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pétérù tẹ̀lé Jésù lókèèrè, ó sì yọ́ wọ inú àgbàlá olórí àlùfáà, ó sì jókòó pẹ̀lú àwọn ọmọ ọ̀dọ̀, ó ń yáná.

Máàkù 14

Máàkù 14:50-59