Máàkù 14:49 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ojoojúmọ́ ni èmi wà pẹ̀lú yín ní tẹ́ḿpìlì, tí mo ń kọ́ni; ẹ kò mú mi. Ṣùgbọ́n eléyìí ṣẹlẹ̀, kí ohun tí ìwé Mímọ́ wí lè ṣẹ.”

Máàkù 14

Máàkù 14:48-53