Máàkù 14:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì lọ ṣíwájú díẹ̀, ó dojú bolẹ̀, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí i gbàdúrà pé, bí ó bá ṣe e ṣe kí wákàtí tí ó bọ̀ náà ré òun kọjá.

Máàkù 14

Máàkù 14:32-38