Máàkù 14:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù wá wí fún un pé, “Jẹ́ kí ń sọ òótọ́ fún ọ. Kí àkùkọ tóó kọ lẹ́ẹ̀kejì ní òwúrọ̀ ọ̀la, ìwọ, pàápàá yóò ti sọ lẹ́ẹ̀mẹ̀ta wí pe ìwọ kò mọ̀ mí rí.”

Máàkù 14

Máàkù 14:24-35