Máàkù 13:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

À fi tí Olúwa bá gé àkókò ìjìyà náà kúrú, ẹyọ ẹ̀mí kan ní ayé kì yóò là. Ṣùgbọ́n nítorí àwọn tí Ọlọ́run yàn, ni yóò ṣe dín àwọn ọjọ́ náà kù.

Máàkù 13

Máàkù 13:11-22