Máàkù 12:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti pé, mo mọ bí ó ti ṣe pàtàkì tó láti fẹ́ ẹ pẹ̀lú gbogbo agbára mi, àti pẹ̀lú pé kí n fẹ́ràn ọmọnìkéjì mi gẹ́gẹ́ bí ara mi, ju kí n rú oríṣiiríṣii ẹbọ lórí i pẹpẹ ilé ìsìn.”

Máàkù 12

Máàkù 12:24-42