Máàkù 11:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n bá ara wọn jíjòrò pé: “Bí a bá wí pé Ọlọ́run ni ó rán an wá nígbà náà yóò wí pé, ‘nígbà tí ẹ mọ̀ bẹ́ẹ̀, èéṣe tí ẹ kò fi gbà à gbọ?’

Máàkù 11

Máàkù 11:21-33