Máàkù 10:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun àti ìyàwó rẹ̀ yóò di ara kan náà. Nítorí náà, wọn kì í tún ṣe méjì mọ́ bí kò ṣe ẹyọ ọ̀kan ṣoṣo.

Máàkù 10

Máàkù 10:3-11